audio
audioduration (s) 0.72
14.2
| text
stringlengths 7
167
| speaker_id
int64 1
1
|
|---|---|---|
Tani ó máa tẹ̀lé mi rìnrìn-àjò lọ sí Kankia ?
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, mo jẹ sùpàgẹ́tì náà tan lánàá.
| 1
|
|
Ṣé ìwọ yóò jẹ́ àlejò mi ní ibi ìpamọ́ ẹran ìgbẹ́ fún ìdárayá ní ọ̀la?
| 1
|
|
Ṣé o máa lọ sí ìsọmọlórúkọ ọmọ Foláyẹmí lọ́la?
| 1
|
|
Kílódé ti o fí n fowó pa ọmọbìnrin náà lára
| 1
|
|
Tani yóò sọ ìtàn fún wa ní alẹ́ òní?
| 1
|
|
Ṣé Tádé yóò ra ṣáájà náà?
| 1
|
|
Ṣé o máa bami ra oúnjẹ ajá mi bọ̀ ni oṣù tó ń bọ̀?
| 1
|
|
Ṣé o ò ní dìdé fún mi ni!
| 1
|
|
Bẹẹni, èmi yóò di olórí àwọn ọmọbìnrin ilé-ìwé yii
| 1
|
|
Ṣé ọmọkùnrin náà yóò gbá bọ́ọ́lù?
| 1
|
|
Ta ló máa tẹ́lè mi lọ sí agbègbè ìdárayá ní ọjọ́ àìkú?
| 1
|
|
béèni Èèrà lọ jé òkú ẹkú yén .
| 1
|
|
Ṣé ọba yóò wá pẹ̀lú ayaba lọ sí àjọ̀dún náà?
| 1
|
|
Ta ló ma gbé mi lọ mọ́ṣáláṣí?
| 1
|
|
Tani Baálẹ̀ abúlé wa tó kàn?
| 1
|
|
Béèni o má ba wa yán gbé.
| 1
|
|
Ṣé ilé ẹ̀kọ́ ma wà fún àwọn afọ́jú ?
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, mo máa lọ sí àjọ̀dún ọdún egúngún náà.
| 1
|
|
Ṣe wa dáná ni ọ̀túnla?
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ ni, Adé ra búrékì tuntun.
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, ọlá ni ó ni ilé ọtí yìí
| 1
|
|
Ṣé Tọ́pẹ́ yóò fi àwòrán sórí WhatsApp rẹ̀?
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, mo ti pàdé ọmọ rẹ obìnrin
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, apabidà pupa ni mo lo fún ikọ́ mi.
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, mo máa kúrò nínú ibùgbé tálákà ní ọjọ́ kan.
| 1
|
|
béèni , o so èdè Itálíà teletele.
| 1
|
|
Ṣé wàá gbà ṣọ́ọ́bù ṣí ọjà oun ikole láti máà ta àwọn ọjà jórinjórin rẹ ?
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ ni, mo mọ òfin ìjàkadì.
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni mo ti dan wò
| 1
|
|
Ṣe o ni sọ fún wa nkán ti a fẹ jẹ fún oúnjẹ aarọ?
| 1
|
|
Béèni oúnjẹ ti o feran ju ní ẹwà.
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ ni, yóò jẹ àpọ̀n.
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, mo gbà àwẹ̀ lásìkò Ramadan.
| 1
|
|
Sé wàá padà wá lọ́la fún ìwé tí ó n sàlàyé bí o ti náwo?
| 1
|
|
Ṣé Àrẹ̀mú máa gbá bọ́ọ̀lù lọ́la?
| 1
|
|
Béèni, Èmí yóò kán si Oluko tí Òfin
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, lọ sí ìkànnì ibanidọ̀rẹ́ WhatsApp.
| 1
|
|
Tani yóò mu ọ́kọ wa lọla?
| 1
|
|
Ṣé o ma lọ wọ ọkọ̀ ni ibùdó ọkọ lọ́la?
| 1
|
|
Kìlọ fà ìjà làrin àwọn àbúrò bàbá rè?
| 1
|
|
Béèni wón mú Irúgbìn músítádì Wá.
| 1
|
|
Tani yóò ṣe ìpè òhun pẹ̀lú rẹ?
| 1
|
|
Ṣé àwọn èèyàn púpọ̀ yóò wà ní ibi ìgbéyàwó náà?
| 1
|
|
Ǹjẹ́ wà á lọ sí òde alẹ́ náà?
| 1
|
|
So máa ro oko?
| 1
|
|
Ṣé Akin yóò lọ fún ètò náà ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ áátì?
| 1
|
|
ṣe o má sọ òtítọ́ fún àwọn ti o ku?
| 1
|
|
Ọba wo nìyẹn?
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, mo yanjú àlọ́ àpamọ́ náà
| 1
|
|
Tani yóò gbe ounje lọ si ọgba ẹ́wọ̀n?
| 1
|
|
Ṣe o ma máa ṣe iṣẹ amurele rẹ ni ilé?
| 1
|
|
Ṣé o máa kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìkọ̀ròyìn?
| 1
|
|
Bèéni, mo fẹ́ mọ bí wọn ṣé ń mọ ìkòkò.
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ ni, mò ń lọ sí orí-okè Àsábarí.
| 1
|
|
Ṣé wá lọ bá mi bá próvòstì?
| 1
|
|
Ẹn, ó kọ ìyàwó rẹ̀.
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, mo gba ìkíni àti ádùrá rẹ̀
| 1
|
|
Tani òó se ọdún kérésìmesì pẹ̀lú ní osù tó ń bọ̀
| 1
|
|
Pẹlu kiikan ti AI, awọn olukọ yóò maa dinku
| 1
|
|
Beeni, mo je Tuwo ati Gbẹ̀gìrì.
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, mo máa ra múdúgáàdì tuntun
| 1
|
|
Bẹẹni, Mo wá ni ọna lo si yàrá ìkàwé
| 1
|
|
Ǹjẹ́ wà á lo òwú yìí láti nu ojú ẹgbò rẹ?
| 1
|
|
ṣe Tade yíò lọ rí dókítà nítorí Etí rẹ ?
| 1
|
|
Béèni, o jẹ ọmọ ilé-ìwé gíga
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, mo ti bá ìyàwó ẹ sọ̀rọ̀
| 1
|
|
Ta ló páàkì sí gáràjì náà ní alẹ́ àná?
| 1
|
|
Ṣé wà á fá irun orí ọmọ rẹ àti pé ṣẹ́ wà á pa ẹran?
| 1
|
|
Bẹẹni a le ṣe awọn apeere
| 1
|
|
Ǹjẹ́ o óò di Irun mi?
| 1
|
|
Béèni Lọla má wá sí ààyè ìgbà Bọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀.
| 1
|
|
Ṣé ìyálóde máa wá sí ìpàdé àwọn obìnrin?
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, mo jẹ núdùsì
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, òwe náà yé mi.
| 1
|
|
Béèní, o ti se ìmúniwẹgbẹ́ làná
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ ni, èmi ni awakọ̀ òfurufú náà.
| 1
|
|
Béèni Òré méjèjì bó ira wón lówó láti kí àrà wón.
| 1
|
|
Ṣé Akin yóò wọ ọkọ̀ ojú-omi ńlá tó ń lọ Berlin?
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, Ahmed ṣe ẹja páì fún ìdíje ìdáná ní ọdún tó kọjá.
| 1
|
|
Wọ́n máa ń sábà ṣàpèjúwe àwọn obìnrin gẹ́gẹ́ bí ẹlẹ́wà.
| 1
|
|
Ṣé wà á lọ sí ìpàdé ẹgbẹ́ àwọn ọmọ Odùduwà?
| 1
|
|
Ṣe àwọn oyin yìí máa yé ẹyin láyìpẹ́?
| 1
|
|
Béèni wón gbà Bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá .
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, mo lè jẹ èso ọ̀pẹ̀yìnbo.
| 1
|
|
ṣe ìdáná onígáàsì ní o má lo lati ṣe oúnjẹ?
| 1
|
|
Njẹ Adebayo ọ ṣe ìgbéyàwó laipẹ?
| 1
|
|
Sé yóò di Irun rè?
| 1
|
|
Ta ló lọ sí ọgbà-ìṣeré lánàá?
| 1
|
|
Bẹ́ẹ̀ni, ọ̀gẹ̀dẹ̀ ni mo ń jẹ
| 1
|
|
Ṣé ọ̀la ni ó máa kan ilẹkùn yìí pẹ̀lú ìṣó?
| 1
|
|
Ṣé o máa wà ní ilé ìtajà ńlá?
| 1
|
|
Iṣu ṣe jẹ́ oríṣiríṣi nkan.
| 1
|
|
Ṣe iwọ yóò se ife Ìrẹsí kàn?
| 1
|
|
Ǹjẹ́ o óò Ra ilé-iṣẹ́ ìfọ̀po náà?
| 1
|
|
Béèni mọ má ló Réèkì pá àwọn koríko yén pọ .
| 1
|
|
Kí ló dé tí àwọn ènìyàn fi péjọ lábẹ́ òṣùpá fún eré ìdárayá?
| 1
|
|
Ṣe iwọ o kó awọn Àgbo yẹn jọ?
| 1
|
|
Ṣé wà wá gbọ àlọ́ lọla?
| 1
|
|
Ṣé o máa wá sí ibi ìpéjọ abúlé náà?
| 1
|
End of preview. Expand
in Data Studio
No dataset card yet
- Downloads last month
- 8