audio audioduration (s) 0.72 14.2 | text stringlengths 7 167 | speaker_id int64 1 1 |
|---|---|---|
Tani ó máa tẹ̀lé mi rìnrìn-àjò lọ sí Kankia ? | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, mo jẹ sùpàgẹ́tì náà tan lánàá. | 1 | |
Ṣé ìwọ yóò jẹ́ àlejò mi ní ibi ìpamọ́ ẹran ìgbẹ́ fún ìdárayá ní ọ̀la? | 1 | |
Ṣé o máa lọ sí ìsọmọlórúkọ ọmọ Foláyẹmí lọ́la? | 1 | |
Kílódé ti o fí n fowó pa ọmọbìnrin náà lára | 1 | |
Tani yóò sọ ìtàn fún wa ní alẹ́ òní? | 1 | |
Ṣé Tádé yóò ra ṣáájà náà? | 1 | |
Ṣé o máa bami ra oúnjẹ ajá mi bọ̀ ni oṣù tó ń bọ̀? | 1 | |
Ṣé o ò ní dìdé fún mi ni! | 1 | |
Bẹẹni, èmi yóò di olórí àwọn ọmọbìnrin ilé-ìwé yii | 1 | |
Ṣé ọmọkùnrin náà yóò gbá bọ́ọ́lù? | 1 | |
Ta ló máa tẹ́lè mi lọ sí agbègbè ìdárayá ní ọjọ́ àìkú? | 1 | |
béèni Èèrà lọ jé òkú ẹkú yén . | 1 | |
Ṣé ọba yóò wá pẹ̀lú ayaba lọ sí àjọ̀dún náà? | 1 | |
Ta ló ma gbé mi lọ mọ́ṣáláṣí? | 1 | |
Tani Baálẹ̀ abúlé wa tó kàn? | 1 | |
Béèni o má ba wa yán gbé. | 1 | |
Ṣé ilé ẹ̀kọ́ ma wà fún àwọn afọ́jú ? | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, mo máa lọ sí àjọ̀dún ọdún egúngún náà. | 1 | |
Ṣe wa dáná ni ọ̀túnla? | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ ni, Adé ra búrékì tuntun. | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, ọlá ni ó ni ilé ọtí yìí | 1 | |
Ṣé Tọ́pẹ́ yóò fi àwòrán sórí WhatsApp rẹ̀? | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, mo ti pàdé ọmọ rẹ obìnrin | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, apabidà pupa ni mo lo fún ikọ́ mi. | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, mo máa kúrò nínú ibùgbé tálákà ní ọjọ́ kan. | 1 | |
béèni , o so èdè Itálíà teletele. | 1 | |
Ṣé wàá gbà ṣọ́ọ́bù ṣí ọjà oun ikole láti máà ta àwọn ọjà jórinjórin rẹ ? | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ ni, mo mọ òfin ìjàkadì. | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni mo ti dan wò | 1 | |
Ṣe o ni sọ fún wa nkán ti a fẹ jẹ fún oúnjẹ aarọ? | 1 | |
Béèni oúnjẹ ti o feran ju ní ẹwà. | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ ni, yóò jẹ àpọ̀n. | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, mo gbà àwẹ̀ lásìkò Ramadan. | 1 | |
Sé wàá padà wá lọ́la fún ìwé tí ó n sàlàyé bí o ti náwo? | 1 | |
Ṣé Àrẹ̀mú máa gbá bọ́ọ̀lù lọ́la? | 1 | |
Béèni, Èmí yóò kán si Oluko tí Òfin | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, lọ sí ìkànnì ibanidọ̀rẹ́ WhatsApp. | 1 | |
Tani yóò mu ọ́kọ wa lọla? | 1 | |
Ṣé o ma lọ wọ ọkọ̀ ni ibùdó ọkọ lọ́la? | 1 | |
Kìlọ fà ìjà làrin àwọn àbúrò bàbá rè? | 1 | |
Béèni wón mú Irúgbìn músítádì Wá. | 1 | |
Tani yóò ṣe ìpè òhun pẹ̀lú rẹ? | 1 | |
Ṣé àwọn èèyàn púpọ̀ yóò wà ní ibi ìgbéyàwó náà? | 1 | |
Ǹjẹ́ wà á lọ sí òde alẹ́ náà? | 1 | |
So máa ro oko? | 1 | |
Ṣé Akin yóò lọ fún ètò náà ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ áátì? | 1 | |
ṣe o má sọ òtítọ́ fún àwọn ti o ku? | 1 | |
Ọba wo nìyẹn? | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, mo yanjú àlọ́ àpamọ́ náà | 1 | |
Tani yóò gbe ounje lọ si ọgba ẹ́wọ̀n? | 1 | |
Ṣe o ma máa ṣe iṣẹ amurele rẹ ni ilé? | 1 | |
Ṣé o máa kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìkọ̀ròyìn? | 1 | |
Bèéni, mo fẹ́ mọ bí wọn ṣé ń mọ ìkòkò. | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ ni, mò ń lọ sí orí-okè Àsábarí. | 1 | |
Ṣé wá lọ bá mi bá próvòstì? | 1 | |
Ẹn, ó kọ ìyàwó rẹ̀. | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, mo gba ìkíni àti ádùrá rẹ̀ | 1 | |
Tani òó se ọdún kérésìmesì pẹ̀lú ní osù tó ń bọ̀ | 1 | |
Pẹlu kiikan ti AI, awọn olukọ yóò maa dinku | 1 | |
Beeni, mo je Tuwo ati Gbẹ̀gìrì. | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, mo máa ra múdúgáàdì tuntun | 1 | |
Bẹẹni, Mo wá ni ọna lo si yàrá ìkàwé | 1 | |
Ǹjẹ́ wà á lo òwú yìí láti nu ojú ẹgbò rẹ? | 1 | |
ṣe Tade yíò lọ rí dókítà nítorí Etí rẹ ? | 1 | |
Béèni, o jẹ ọmọ ilé-ìwé gíga | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, mo ti bá ìyàwó ẹ sọ̀rọ̀ | 1 | |
Ta ló páàkì sí gáràjì náà ní alẹ́ àná? | 1 | |
Ṣé wà á fá irun orí ọmọ rẹ àti pé ṣẹ́ wà á pa ẹran? | 1 | |
Bẹẹni a le ṣe awọn apeere | 1 | |
Ǹjẹ́ o óò di Irun mi? | 1 | |
Béèni Lọla má wá sí ààyè ìgbà Bọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀. | 1 | |
Ṣé ìyálóde máa wá sí ìpàdé àwọn obìnrin? | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, mo jẹ núdùsì | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, òwe náà yé mi. | 1 | |
Béèní, o ti se ìmúniwẹgbẹ́ làná | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ ni, èmi ni awakọ̀ òfurufú náà. | 1 | |
Béèni Òré méjèjì bó ira wón lówó láti kí àrà wón. | 1 | |
Ṣé Akin yóò wọ ọkọ̀ ojú-omi ńlá tó ń lọ Berlin? | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, Ahmed ṣe ẹja páì fún ìdíje ìdáná ní ọdún tó kọjá. | 1 | |
Wọ́n máa ń sábà ṣàpèjúwe àwọn obìnrin gẹ́gẹ́ bí ẹlẹ́wà. | 1 | |
Ṣé wà á lọ sí ìpàdé ẹgbẹ́ àwọn ọmọ Odùduwà? | 1 | |
Ṣe àwọn oyin yìí máa yé ẹyin láyìpẹ́? | 1 | |
Béèni wón gbà Bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá . | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, mo lè jẹ èso ọ̀pẹ̀yìnbo. | 1 | |
ṣe ìdáná onígáàsì ní o má lo lati ṣe oúnjẹ? | 1 | |
Njẹ Adebayo ọ ṣe ìgbéyàwó laipẹ? | 1 | |
Sé yóò di Irun rè? | 1 | |
Ta ló lọ sí ọgbà-ìṣeré lánàá? | 1 | |
Bẹ́ẹ̀ni, ọ̀gẹ̀dẹ̀ ni mo ń jẹ | 1 | |
Ṣé ọ̀la ni ó máa kan ilẹkùn yìí pẹ̀lú ìṣó? | 1 | |
Ṣé o máa wà ní ilé ìtajà ńlá? | 1 | |
Iṣu ṣe jẹ́ oríṣiríṣi nkan. | 1 | |
Ṣe iwọ yóò se ife Ìrẹsí kàn? | 1 | |
Ǹjẹ́ o óò Ra ilé-iṣẹ́ ìfọ̀po náà? | 1 | |
Béèni mọ má ló Réèkì pá àwọn koríko yén pọ . | 1 | |
Kí ló dé tí àwọn ènìyàn fi péjọ lábẹ́ òṣùpá fún eré ìdárayá? | 1 | |
Ṣe iwọ o kó awọn Àgbo yẹn jọ? | 1 | |
Ṣé wà wá gbọ àlọ́ lọla? | 1 | |
Ṣé o máa wá sí ibi ìpéjọ abúlé náà? | 1 |
End of preview. Expand
in Data Studio
No dataset card yet
- Downloads last month
- 14